HYMN 205

1.	Olorun Oba Imole

	Oba aiye raiye e,

	Ologo didan julo,

	Waju eniti,

	Kekere ninu ese,

	Ki yio le sunmo O,

	To nfi ife pee lese

	Lati r’ogo Re.


2.	Awon ti o fe lo npe,

	Awon to pe loyan a

	Awon to yan lo se l’ogo,

	Laiye okunkun,

	Aiye nko ipe na,

	Nwon rin sinu okunkun,

	Lai re ronupiwada,

	Labe iparun.


3.	Ire t’ale logba Eden,

	Ronupiwada a,

	Wa si ibugbe Imole,

	Ibugbe Ife,

	Nibiti Jesu njoba,

	Niwaju ite Baba,

	Elese ronupiwada,

	Ma ko ipe na. 	Amin

English »

Update Hymn