HYMN 431

1.  Oluwa, awa omo re de,

     Lati gbohun ebe wa soke 

     Gegebi o ti gbo adura Elijah,

     Jowo gbo adura wa.


2.  O gbadura kojo mase ro,

     Fun odun meta, on osu mefa 

     Gegebi o ti gbo adura Elijah,

     Jowo gbo adura wa.


3.  O si tun gbadura lekeji,

     Ojo ro, ile si meso wa, 

     Gegebi o ti gbo adura Elijah,

     Jowo gbo adura wa.


4.  Adura lo n silekun anu,

     Adura lo si Anna ninu,

     Gegebi o ti gbo adura Elijah,

     Jowo gbo adura wa. Amin

English »

Update Hymn